Owo Lyrics by Reminisce
Reminisce Lyrics
Check out the official lyrics for Owo by Reminisce below. Owo is the fifth track on Reminisce’s newly released EP, Sui Generis.
RELATED: Read ‘Up As Fxck’ Lyrics by Reminisce Feat. BadBoy Timz
Reminisce – Owo Lyrics
Eni fe nawo, na mi lowo kia
Ajilete mo ti n wa, lona Ipokia
Owo n be lapo mi o
Owo n be lapo mi o
Eni a ba laba ni baba
Eni ba se jura e lo a jegba
I don’t care what they say about me
Ki ma fagbo lo ni temi Akanbi
Owo n be lapo mi o
Owo n be lapo mi o
Owo n be lapo mi o
Owo n be lapo mi o
Ki ma fagbo lo ni temi Akanbi
Ki ma ge lo ni temi Akanbi
Keyin kan maa jisoro
Ke kan maa jisoro, kan maa jisoro
Kan maa jisoro
Kan maa jisoro Akanbi
Owo n be lapo mi o
Owo n be lapo mi o
Owo n bẹ lapo mi o (Owo n be lapo mi o)
Ẹ kan maa jisoro, kan maa jisoro wa
Kan maa jisoro wa, kan maa jisoro Akanbi
Owo n be lapo mi o
Omoge ma foju di mi
To ba foju di mi
O de ti mo tipetipe
Wa jogede, wa momi le, wa jegba ni tibi
Ki ma fagbo lo ni temi Akanbi
Ki ma ge lo ni temi Akanbi
Keyin kan maa jisoro
E kan maa jisoro, kan maa jisoro wa
Kan maa jisoro wa, kan maa jisoro Akanbi
Ki ma ge lo ni temi Akanbi
Keyin kan maa ji soro (Owo n be lapo mi o)
Ke kan maa jisoro, kan maa jisoro, kan maa jisoro
Kan maa jisoro wa, kan maa jisoro wa, kan maa jisoro wa
Owo n be lapo mi o (Owo n be lapo mi o)
Owo n be lapo mi o
Owo n be lapo mi o
E kan maa jisoro, kan maa jisoro wa
Kan ma jisoro wa, kan ma jisoro Akanbi
Owo n be lapo mi o
Find and explore other lastest song lyrics here
Get Fresh updates as they drop via X (formerly Twitter) and Facebook
The post Owo Lyrics by Reminisce appeared first on NotjustOk.
Leave a Reply